[Intro] Oya ma lo sunn, Ko le sun yara ti ko ni lekun, ewuree wo be lo sun…. Ahh! My blood, my blood Fresh! Astalivi give them
[Verse 1 – Slimcase] Okay, o ti ko si owo aye, (o ti ko si owo aye) O ti wo’nu IG (Ah! o ti wo’nu IG) O’n ti wa content, O’n ti wa repost (O fe wa repost) O tin gbon’di gbuse, So idi gegege, idi gbonlebe gede Idi’wese
[Chorus] Awon omo isin pongilah kan le la, Awon omo isin pongilah pongilah (Pongi) Awon omo isin Pongilah kan le la, Awon omo isin pongilah pongilah pongilah Awon omo isin pongilah kan le la, Awon omo isin pongilah pongilah Awon omo isin Pongilah kan le la, (won pongi) Awon omo isin pongilah pongilah ponwon la
[Verse 2] Otunba lamba, (Otunba lamba) Won l’oti tun mugbe le (o fe mu gbe le) O’n ti’n ta won, ta won, bi won shey won shey da’ko ni Enu e shey wa n yo, s’olo ijabe ni, Ara to ma san pawon n fagbo lowo oh Fagbo ti e, kin fa temi, k’eruku igbo kan ma lo Di’kan lo’wo oh (…Baba) Coaste, coaste, coaste, coaste Omi oyan lo’dun ju, e ma wo isu obo o ga ju Omi oyan lo’dun ju, e ma wo isu obo o ga ju
[Chorus] Awon omo isin pongilah kan le la, Awon omo isin pongilah pongilah (Pongi) Awon omo isin Pongilah kan le la, Awon omo isin pongilah pongilah pongilah Awon omo isin pongilah kan le la, Awon omo isin pongilah pongilah Awon omo isin Pongilah kan le la, (won pongi) Awon omo isin pongilah pongilah ponwon la
[Verse 2 – Zlatan Ibile] Shebi Oloun lo da obo, (obo) Eniyan lo de da dido Wa fe lo fun e wo, iwo lo ma jawon pe iwo ko ni iko Di e ni omo okunrin se ko’to, Kini yen se o ni dido O ni la ti kan left and right, k’an mo pe iwo gan set arrow Igboro ni mi omo Havana, e le fe mi pa (Never) Mi need la ti je Jay Jay, ki e to mo pe omo igboro ni mi, pe mo clever Omo ogbon, omo ogbon, eja to wa ninu odo e le je tan (bawo ni e se fe si) Lamba Slimcase e le gbo tan, Zlatan Ibile lo confirm e, Iya eh Astalivi
[Outro] Oya ma lo sunn, (mo ni ma lo sun) Ko le sun yara ti ko ni lekun, ewuree wo be lo sun…. (Ahhh curtain lo fisii)
Okay
Egeregetuma Abarakatuma Odoo o baby Ijo makosa Shey o le gbe iya yen Shey enu e bo Slimcase, Zlatan Oya dagboro, dagbobi